Wiki Fẹ́ràn Ilẹ̀ Áfíríkà 2025

jẹ́ ìdíje ti ilẹ̀ Áfíríkà tó tóbi jù lọ,
tó ní ṣe pẹ̀lú àwòrán, fọ́nrán àti ohùn.
Àkòrí ti ọdún 2025 ni Oko sí Abọ́
Darapọ̀ mọ́ wa! BẸ̀RẸ̀ NÍ ỌJỌ́ KÌÍNÍ OṢÙ KẸTA ỌDÚN!
Nínú ọ̀kẹ́ àìmoye àwọn àyọkà tí o lè kà lórí Wikipedia, ìwọ̀ǹba péréje ni àwọn èyí tó dá lórí ilẹ̀ Áfíríkà. Èyí ní ṣe pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìdí, àmọ́ àwọn kan ní ṣe pẹ̀lú pé ọ̀pọ̀ ènìyàn ò mọ̀ pé wọ́n lè ṣe àkọ́sílẹ̀ àwọn ohun tó jẹ mọ́ orílẹ̀-èdè wọn, àti àṣà wọn lórí Wikipedia nípa ṣíṣe àdàsílẹ̀ àwòrán, fọ́nrán àti ohùn sí orí Wikimedia. Ó pọn dandan kí a ṣe ìgbélárugẹ àṣà, ẹwà àti àwọn ohun àmúyẹ ilẹ̀ Áfíŕkà sórí Wikipedia.

Ìwọ lè ràn wá lọ́wọ́ láti ṣe èyí. Ó rọrùn gidi gan-an ni, a sì kí gbogbo ènìyàn káàbọ̀ láti darapọ̀ mọ́ ìdìje náà!
=== Kí ni kí ÌWỌ ṣe láti dá si?
Àwòrán! Ohun! Fọ́nrán!===
Àkòrí tó sọ pé Oko sí abọ́ ń pè fún ìfàkalẹ̀ mídíà (àwòrán, ohun, fọ́nrán) tó ní ṣe pẹ̀lú oko, iṣẹ́ àgbẹ̀, erè oko, irinṣẹ oko, àwọn ènìyàn tí ń roko, yíyí oúnjẹ padà, síse oúnjẹ, ilé-oúnjẹ,oúnjẹ lórí abọ́, àwọn ohun èlò oúnjẹ àti gbogbo ìgbésẹ̀ tó ní ṣe pẹ̀lú síso er̀ oko di oúnjẹ jíjẹ.
Kà sí i nípa àkòrí, kí o sì gba ìwúrí níbí.
Àwọn àwòrán ìsàlẹ̀ yìí ṣàpèjúwe àwọn apá kan nínú àkòrí, wọ́n sì wà láti fún ọ ní ìwúrí!
Wikipedia ń lo àwọn ìwé-àṣẹ Creative Commons. Kí ni èyí túnmọ̀ sí?
Ìgbésẹ̀ márùn-ún tó rọrùn láti fi darapọ̀!
- Lo àwọn fọ́nrán tó jẹ mọ́ àkòrí Oko sí Abọ́
- [$ Ṣẹ̀dá àkọsílẹ̀ ọ̀fẹ́] tàbí forúkọ wọlé lórí Wikimedia Commons.
- Kàn sí Láti Wọlé ojú-èwé wa fún àmọ̀ràn lórí gbogbo ohun tó rọ̀ mọ́ ìdíje náà.
- Ri dájú wí pé o tẹ̀lé àwọn ofin ìdíje náà(àjẹ́ bẹ́ẹ̀ àwòrán rẹ̀ ò ní yege!)
- Gbé àwọn àwòrán rẹ̀ sórí - láti ọjọ́ kìíní oṣù kẹta ọdún 2025 lọ!
Ohun tó ṣe pàtàkì
Lo àwọn àwòrán tàbí mídíà tó bá àkòrí náà lọ ní èyí tó jẹ mọ́ ilè "Áfíríkà".
Láti yege, àwọn àfàkalẹ̀ gbọdọ̀ jẹ́ èyí tó wà ní ìbámu pẹ̀lú ìwé-àṣẹ (ka nípa àwọn ìwé-àṣẹ níbí).
Gbá kámẹ́rà rẹ, ya àwòràn ilẹ̀ Áfíríkà rẹ!
Àwọn ẹ̀bùn wo ni mo lè jẹ?
There are several prizes up for grabs for quality entries: both at a national and international level. For national prizes, see what local organisers have planned in your country.
At the international level, there are several main prize categories for Wiki Loves Africa + other additional prizes for the 2025 theme.
|
Wiki Loves Africa 2025: International Prize Categories
Photography:
Media (Video, Audio, Graphics, Photo Essays):
|
|
Disclaimer: Prize money may be dispensed in a gift card or voucher format
- For information on how to submit a Special Collection or Photo Essay, click here
Selecting the Winners
The winners will not be selected until July 2025. They will be announced in August 2025 at Wikimania.
In the meanwhile,
- Review the Jury Process on the 2025 International Jury page
- Take a look at the 2025 Jury members
- View all the winners from previous Wiki Loves Africa
Spread the word! Follow us and keep up-to-date!
Official Wiki Loves Africa website
Wiki Loves Africa on Instagram
Press kits and Media materials
Àwọn Alábàáṣiṣẹ́pọ̀ Olùṣètò ní Agbègbè
![]() |
![]() |
![]() |
![]() |
![]() |
![]() | |
![]() |
![]() |
![]() |
![]() |
![]() |
![]() | |
![]() |
![]() |
![]() |
![]() |
![]() |
![]() |
![]() |
![]() |
![]() |
![]() |
![]() |
![]() |
![]() |
![]() |
![]() |
Àwọn Alábàáṣiṣẹ́pọ̀ Olùṣètò ní Agbègbè láìsí àmì
Planning Wikimedia Community User Group Burundi • Central African Republic Volunteer Group • Ethiopian Wikimedia Volunteer Group • Wiki For Senior Citizens Network (Nigeria) • WikiZimbabwe Volunteer Group • Wikimedia Angola • Wikimedia Community User Group Gabon • Igala Wikimedia Community